Take a fresh look at your lifestyle.

Osinbanjo ń darí ìpàdé pàjáwìrì ìgbìmò ètò ọrọ̀ ajé

Ademọla Adepọju

86

Igbákejì àar̀ẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ọjogbon Yemi Osinbajo, ni olùdarí ìpàdé pàjáwìrì ìgbìmò ètò ọrọ̀ ajé tó bèrẹ̀ ní àárọ̀ ọjọ́ Ẹtì ní́í aago mọ́kànlá.

Ìpàdé ìgbìmò naa maa ń wáyé ní ọjọ́bọ̀ keta ,osù. Àmọ́ ìpàdé pàjáwìrì naa wáyé ní ọjọ́ Jimọh àkọ́kọ́ osù tí a wà yíí.

Síbẹ̀síbẹ̀, ko si ti si alaye lori nnkan ti ipade naa da le lori.

Siwaju si, ipade ti awọn igbimo eto ọrọ aje se kẹyin, ni wọn ti pinnu lati se ijiroro lori atunse nipa abajade ti awọn igbimọ to n se atunse lori eto idajọ nipa ifẹhonuhan ti awọn EndSARS se, ti o waye ni orilẹ-ede Naijiria ni ọdun to kọja.

Lori ẹrọ ayelujara ni igbakeji aarẹ orilẹ-ede Naijiria, Osinbajo ti n se ipade ọhun ni ọfisi ilẹ aarẹ to wa niluu Abuja. Gbogbo awọn gomina to wa lorilẹ ede Naijiria ni wọn darapọ mọ ipade ọhun lati ipinlẹ wọn.

 

 

 

 

Hamzat Roshidat

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.