Àwa la kọlu ilé Sunday Igboho, a sì tún ń lé pa rẹ̀- Ilé-isẹ́ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́(DSS)
Ademọla Adepọju
Ilé-isẹ́ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ , ti a mọ̀ sí, Department of State Security Service( DSS) ti ní ilé-isẹ́ DSS àti agbófinró ni wọ́n kọlu ilé , Sunday Adeniyi Adeyemo a.k.a. SUNDAY IGBOHO ni Soka, tó wà nílùú Ìbàdàn, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ .
Alukoro fun ile-isẹ ọhun, ọgbẹni Peter Afunanya lo sọ eleyii lasiko to n ba awọn akọroyin sọrọ niluu Abuja, ti o jẹ olu-ilu orilẹ ede Naijiria.
ile-isẹ DSS tun salaye awọn ohun ija ogun ati awọn ibọn oloro ti wọnko nile Sunday Igboho, lara wọn ni :
- Ibọn meje (7) AK-47 assault rifles;
- Ibọn mẹta (3) Pump Action guns;
iii. TIbọn ado oloro ọgbọn (30) fully charged AK-47 magazines;
- Ado oloro ẹgbẹrun marun un (5,000) rounds of 7.62mm ammunition;
- Àdá marun un (5) , ọ̀bẹ (1) Jack , One (1) Pen Knife
- Ibọn meji (2) Pistol holsters;
vii. One (1) binoculars
viii. Dọla marun un owo ilẹ okeere (5) US (1) Dola, owo ilẹ okeere; iwe irinna ọkọ̀ ti orilẹ ede yii ati ti ilẹ okeere , Kadi ti wọn fi n gba owó lẹnu ẹrọ, ATM Cards, iwe igbelu ti orilẹ ede German y, No. YO2N6K1NY , ni eyi ti o ni orukọ rẹ̀;
- Fèrè meji (2) ;
- Ọta ibọn aadọta (50) Cartridges;
- ẹrọ ibaraẹnisọrọ mẹrindinlogun (18) Walkie-Talkies;
xii. Oògùn ati ayẹta ihamọra mẹta (Three) Voodoo charm jackets/;
xiii. Two (2) Laptops (One (1) Toshiba ati One (1) Compaq); and
xiv. Iwe irinna ati awọn nnkan oloro miran .
Afunnaya tun tẹsiwaju pe awọn afurasi mẹtala ni wọn tun mu, nile Sunda Igboho :
- Abdulateef OFEYAGBE
- Amoda BABATUNDE aka Lady K (obinrin)
iii. Tajudeen ERINOYEN
- Diakola ADEMOLA
- Abideen SHITTU
- Jamiu NOAH
vii. Ayobami DONALD
viii. Adelabe USMAN
- Oluwafelumi KUNLE
- Raji KAZEEM
- Taiwo OPEYEMI and
xii. Bamidele SUNDAY.
Alukoro ile-isẹ DSS tun tẹsiwaju pe “ Mo rọ Sunday Igboho ki o fi ara rẹ silẹ fun ijọba nitori ko si ẹni to koja ofin,”
Amọsa, gbogbo awọn ti wọn mu nile Sundau Igboho, ni wọn yoo foju bale ẹjọ́.
Leave a Reply