Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari dárò ikú asòfin ìpínlẹ̀ Zamfara

103

Aarẹ orilẹ ede Naijiria, Muhammadu Buhari ti daro iku asoifn ipinlẹ Zamfara, Muhammad Ahmad  .

Awọn agbebọn pa Ahmad loju ọna  Kano sí Shema/Funtua .

Ninu iwe ti aarẹ kọjade lati fi sedaro iku asofin ọhun, aarẹ ni: “Inu mi bajẹ lasiko ti mo gbọ nipa iku asofin ọhun ti awọn agbebọn pa nigba ti o n gbe ọmọ rẹ lọ si papa ọkọ ofurufu to wa ni Kano lati lọ wọ baalu .”

Aarẹ ti wa pasẹ fun awọn agbofinro ati ajọ eleto aabo lati awọn ọdaran ti wọn se isẹ́ ibi naa jade, ki wọn si fi ọwọ́ ofin mu wọn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.