Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ jẹ́ ká fọwọ́sowọ́pọ̀ láti mú ìdàgbàsókè bá ẹ̀ka ìwakùsà lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà- Yemi Osinbajo

Ademọla Adepọju

113

fọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin ìjọba  àti àwọn agbègbè tí wọn ti ń wa ìwakùsà ló leè ,mú ìdàgbàsókè bá  ẹ̀ka ìwakùsà lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà

Igbakeji aarẹ orilẹ ede Naijiria, ọjọgbọn Yemi Osinbajo lo sọrọ yii lori ẹrọ ayelujara lọjọ Ẹti nibi ipade  ti soe , ni eyi ti wọn pe akọle rẹ ni : Ajinde Aisiki wa ti a sin si. 

Ọjọgbọn Osinbajo tun tẹsiwaju pe Ti a ba ṣiṣẹ papọ, a o ko èrè ti o ju  eyi ti a ba da nikan se isẹ́ rẹ̀ lọ , ”

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.