Igbákejì ààrẹ, orilẹ ede Naijria, Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀síńbàjò sọ pé,ìgbìyànjú orílè-èdè láti pèsè oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ilànà láti dẹ́rù bòṣì jákèjádò orilẹ ede Nàìjíríà.
Ọjọgbọn Ọsinbajo lọjọ iṣẹgun sọ eyi di mimọ nibi ti wọn ti ṣi Ifọrọwerọ Apapọ Iṣọkan ti Orilẹ-ede lori Apejọ Awọn Eto Ounjẹ ti Ajọ Agbaye 2021 se niluu Abuja
Ijiroro naa da lori ọna lati ipese ounjẹ lọpọ janturu ati lati ṣaṣeyọri awọn ẹro Idagbasoke alagberọ kẹtadin-logun,
Leave a Reply