Take a fresh look at your lifestyle.

Òfin láti sisẹ́ láti ilé sí ì wà síbẹ̀– COVID-19

Ademọla Adepọju

38

Ìjọba àpapọ̀ tún ti tẹpẹlẹmọ́ òfin láti máa se isẹ́ láti ilé fún àwọn òsìsẹ́ wọn, pàápàá julọ awọn osisẹ ijoba apapọ to wa ni ipele ipo kejila si isalẹ.

Igbimọ ijọba apapọ to n mojuto gbigbogun ti aaruni Covid-19 lorilẹ ede  Naijiria, Boss Mustapha  lo kede rẹ  ni ilu Abuja nibi ifọrọwerọ ti wọn se pẹlu awọn akọroyin.

Leave A Reply

Your email address will not be published.