Take a fresh look at your lifestyle.

ORÍLẸ-ÈDÈ GERMANY SE ÀSEYEGE LÓRÍ ÀWỌN ỌJÀ TÍ WỌN KÓLỌ SÍ ÒKÈ ÒKUN

Ademọla Adepọju

29

Orílẹ-èdè Germany ti sọ àseyege wọn lórí àwọn ọjà tí wọn kó láti orílẹ-èdè wọn lọ sí òkè òkun.

Lọdọọdún ni owó orí ọjà tí wọn n kó lọ láti orílẹ èdè wọn tún lé si, eléyìí sàlàyé nípa akitiyan wọn lórí èkúnwó owó orí  ọjà tí wọn kó lo láti orílè èdè wọn lo sí òkè òkun.

Àwọn ẹkúnwó wà lórí ọjà ohun ọgbìn láti osù Karún ún ọdún 2020,, ti owó orí rọbà àti àwọn ìresì, àgbàdo naa si tún n lé sii.

 

 

 

 

 

 

HAMZAT ROSHIDAT DAMOLA

Leave A Reply

Your email address will not be published.