Take a fresh look at your lifestyle.

Nàíjíríà kò ní jẹ́ kí wọ́n kó ààrùn COVID-19 tuntun wọ́lé nípa gbígba àlà wọn

53

Ìjọba orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ti ní ohun yóò mú ètò ààbò le ní àwọn ojú àlà tó wà káàkiri orílẹ̀ èdè yìí láti leè dènà ààrùn COVID -19 tuntun  tó tún fẹ́ jẹyọ.

Alaga igbmọ ijọba apapọ to n mojuto gbigbogun ti aarun COVID-19 lorilẹ ede Naijiria , Boss Mustapha lo sọ eleyii niluu Abuja,lasiko ifọwọwanilẹniwo pẹlu awọn akọroyin.

Ni   awọn ọsẹ to kọja ni a kede  awọn  igbesẹ ti a n gbe nipa awọn arinrirnajo ti wọn wa lati orilẹ ede Brazil, Turkey ati India. Eyi ni lati dena aarun COVID-19 tuntun miran ti o tun jẹyọ bayii.

Leave A Reply

Your email address will not be published.