Take a fresh look at your lifestyle.

Dí́dá Iṣẹ́ sílẹ̀:Ọ̀gá ajagunfẹ̀yìntì gba ìjọba níyànjú ìfọwọ́sowọ́pọ̀

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

25

Ajagunfẹ̀yìntì ọ̀hún rọ ìjọba láti fàyè gba Àwọn ilé-iṣẹ́ Kékeré àti Alábọ́dé (SMEs) láti dá iṣẹ́ sílẹ̀.

Ọga agba ajagunfẹyinti,Azubuike Ihejirika,pe ipe yii nibi ifilọlẹ aṣẹ ajọ iṣowo Ó  rọ Ìjoba Nàìjíríà láti ṣe ìfowósowópò pẹ̀lú àjọ  Ìṣòwò Àgbáyé (WIEG) láti agbaye ọhun [WIEG], ni orilẹ-ede Naijiria ni ọjọ abamẹta ni ilu Eko.

WIEG wa fun idagbasoke ajọṣepọ agbaye  ti yoo lana iṣowo ti ko  lopin, ti yoo si tun daabobo aṣa awọn  ati ilana-iṣe iṣowo awọn ọmọ ẹgbẹ.

Ihejirika sọ pe, Ijọba Naijiria ati awọn to jọmọọ MDA  gbọdọ ṣe abaṣepọ pẹlu  WIEG nipa ifọrọjomotoro ọrọ  ati pipese ọna iṣowo fun awọn ọmọ Naijiria.

O sọ pe, ajọṣepọ yoo mu irorun ba ṣiṣe ilana iṣowo pẹlu ijọba ti  aarẹ Muhammadu Buhari  n dari.

Leave A Reply

Your email address will not be published.