Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà naa ń dojúkọ ọ̀wọ́ngógó ounjẹ

Ademọla Adepọju

136

Nàìjíríá wà lára àwọn orílẹ̀-èdè mẹ́fà nílẹ̀ Afirika tí wọ́n dojúkọ ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ

ati pe aimọye awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria ni wọn n fi ẹmi ara wọn wewu nitori ounjẹ, ti awọn ẹgbẹ GRFC naa si ti setan lati mu iyàn lori ọwọngogo ounjẹ wa si opin.

Awọn orile-ede miran ti wọn n dojukọ iyàn lori ọwọngogo ounjẹ naa ni Ethiopia, South Sudan, Sudan, Zimbabwe ati Congo.

Gẹgẹ bi iroyin, ọkẹ aimọye awọn eniyan ni wọn n dojukọ iyàn lori ọwọngogo  ounjẹ, le eyi ti o ti se akoba fun awọn eniyan to le ni miliọnu màrúndinlọgọ́jọ ni awọn orilẹ ede marundinlogota lorilẹ ede agbaye.

Iroyin tun sọ pe awọn ohun to n fa  iyàn lori ọwọngogo lori  ounjẹ  ni awọn wahala  to n sẹlẹ laarin  awọn orilẹ-ede kan si orilẹ-ede miran ati iyipada oju-ọjọ.

 

 

 

Hamzat Roshidat Damola

Leave A Reply

Your email address will not be published.