Take a fresh look at your lifestyle.

Ètò ààbò yóò wà fún lílo ẹrọ ayélujárá fún okoowo -Aarẹ Buhari

Ademọla Adepọju

101

Ààrẹ  Muhammadu Buhari ti ní ohun kò ní káàárẹ̀ láti sàtunse tó mọ́nyan lori ṣi ajọ to n mojuto oju ọrun , ki wọn lee túbọ̀ máa daabo bo ìmọ̀ ẹ̀rọ ayélujára ati eto okoowo  nipa lori ẹ̀rọ ayélujára.

Aarẹ sọrọ lasiko to  n sepade pẹlu awọn ọmọ ẹgbẹ ajọ to n mojuto iwadii ati idagbasoke ẹrọ alátagbà lorilẹ ede Naijiria , National Space Council of the National Space Research and Development Agency (NASRDA) nile aarẹ to wa niluu Abuja.

Aarẹ wa pasẹ fun minisita to n mojuto  imọ sayẹnsi ati imọ ẹrọ ,Ogbonnaya Onu,lati seto ilana ọdun marundinlọgbọn fun ajọ to n mojuto eto oju orun , ti yoo gbe wa siwaju igbimọ ijọba apapọ.

Aarẹ tun wa rọ ajọ naa lati fọwọsowọpọ pẹlu awọn ile-isẹ aladaani ati  ajọ miran lati  mu awọn ipinnu wọnyi  sẹ.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.