Take a fresh look at your lifestyle.

Aarẹ Buhari sún ìrìnàjò fún ìtọ́jú ara rẹ̀ lọ sí UK síwájú

Ademọla Adepọju

108

Ìrìnàjò tí ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Muhammadu Buhari fẹ́ gùnĺe lọ sí orílẹ̀ èdè  United Kingdom lónìí yìí , ni o ti sún síwájú di ọjọ́ míràn .

Oluranlọwọ aarẹ lori iroyin ati ikede , Femi Adesina,lo sọrọ yii lọjọ Ẹti .

O tẹsiwaju pe wọn yoo kede ọjọ ti miran ti aarẹ ba tun fẹ lọ si irinajọ naa.

Leave A Reply

Your email address will not be published.