Take a fresh look at your lifestyle.

A ó mú ìgbèrú bá àwọn ilé-isẹ́ aládàáni láti pèsè isẹ́ fún àwọn ọ̀dọ́

Ademọla Adepọju

83

 

A ó mú ìgbèrú bá àwọn ilé-isẹ́ aládàáni láti pèsè isẹ́ fún àwọn ọ̀dọ́

Ìjọba orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti pinnu pé ìjọba òun  kò ní kaarẹ  láti mú ìgbèrú ba àwọn ilé-isé aladaani lọna àti pèse isẹ́ lọ́pọ̀ janturu fún àwọn ọ̀dọ́ tí kò ní isẹ́ lọ́wọ́ lórílẹ́-èdè Nàìjíríà.

Ìjọba apapọ tẹsiwaju pe, oun ko ni kaarẹ lati pẹse awujọ to dara fun awọn ile-isẹ aladaani lati da ile-isẹ silẹ lorilẹ ede Naijriia, bo tilẹ jẹ pe idagbasoke ati igbeeru ti ba awọn ile-isẹ ibaraẹnisọrọ ati  awọn ile-ẹkọ giga lorile ede.

Oluranlọwo pataki fun alakoso ẹkọ, ỌGBẸNI FOLA BANK OLEMOH sọpe awọn yoo se atilẹyin fun awọn ile-isẹ aladani lati ni idagbasoke, Nigbati o n ba awọn olukopa sọrọ ni apejọ keji lori eto ẹkọ fu ti ilẹ afirika ti awọn Association for Formidable Education Development (AFED) dasilẹ ni agbegbe Kubwa, ni ilu Abuja.

Awọn Aṣoju oluranlọwọ kan, Favour Ilori ati Mr Olemọh se akiyesi pe awọn ile-ekọ aladaani giga ti wọn n pese ti dinku awọn ọmọ ile-iwe ti wọn n wa ile-eko giga ti ijoba tio gbawọn gẹgẹbi awọn idoko-owo aladani ni awọn ibaraenisọro ti ṣii awọn ila aayẹlujara fun awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria.

O si tun  rọ awọn oludokoowo lati ṣawari awọn agbegbe fun idoko-owo wọn

 

 

 

 

Hamzat Roshidat Damola

Leave A Reply

Your email address will not be published.