Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti ṣetán fún ìyẹ̀wò àtúńyẹ̀wò ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ kejì -Ilé iṣẹ́ ààrẹ

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

156

Ìjoba Nàìjíríà sọ pé òhun ti ṣetán fún àjọ tó ń rí sí ìdàgbàsókè ìlú adúláwọ̀ láti sàtúńyẹ̀wò ẹlẹ́gbẹ́ kejì orílẹ̀-èdè  ara ẹni.

Agbẹnusọ fun aarẹ, Femi Adesina ṣe afihan eyi ni ọjọọru, lakoko ti o n ṣalaye fun Awọn oniroyin olu Ile,  ni opin ipade igbimọ ijọba apapọ ti ọsẹ yii,ti aarẹ Muhammadu Buhari ṣe adari rẹ. O sọ pe Aare Buhari ti fọwọsi pe ki ayẹwo naa ko maa waye nibi  ipade  Igbimọ Alaṣẹ apapọ ọlọsọọsẹ.

Agbẹnusọ fun aarẹ ṣe akiyesi pe, ọpọlọpọ ilọsiwaju ti wa, laarin igba ti o ṣe ayẹwo to kẹhin ati lọwọlọwọ bayi.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.