Take a fresh look at your lifestyle.

Òpin yóò dé̀ bá ààrùn Covid-19 ni ilẹ adúláwò- W.T.O

Adepoju Ademola

53

Orilẹ-edé Afirika ti n  sisẹ pẹlu ajọ European Union áti áwọn álábásisẹpọ míiran láti sé iranlọwọ fúndia ile-ise ti yoo ba ma pese abẹrẹ  ájẹsárá ni áwọn ágbegbe  kan ni south Africa, Senegal, Rwanda, ati  orilẹ Níájíriá ti o si wa labẹ ijiroro .

Oludári fun eto okoowo ni ágbáye Ngozi Okonje-Iweala lo sọ eleyii di mimọ lori ẹrọ ayelujara .

 

 

 

 

Abdulrafiu Kehinde

Leave A Reply

Your email address will not be published.