Take a fresh look at your lifestyle.

Ikọ ọmọ ogun ọlọ̀tẹ̀ wọ̀yá ìjà pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun farase lórílẹ̀ èdè Mali

Ademola Adepoju

0 247

Ikọ ọmọ ogun ọlọ̀tẹ̀ lo  ọkọ ogun ayọkẹlẹ  wọn lati kọlu  àwọn ọmọ  ogun farase lórílẹ̀ èdè Mali.

Ọkọ ogun  ayọkẹlẹ ọhun ni wọn fi doju  ijá kọ ikọ ọmọ ogun farase lorilẹ ede  Mali ni ọjọ Aje, ti ọmọ ogun mẹf ati ará ìlú mẹrin si farapa nibi isẹlẹ ọhun, gẹgẹ bi ọkan lara ikọ ọmọ ogun faranse se  sọ.

Ko si ikọ ọmọ ogun ti o gba pe ohun lo kọkọ  bẹrẹ ikọlu naa, ṣugbọn  ikọ ọmọ ajijagbara  musulumi ti o wa pẹlu  al Qaeda áti orilẹ-ede ti o jẹ  múśulúmi ti wọn wa ni agbegbe naa., sọ pe o t́o marun un le laadọta  ikọ ọmọ ogun  fáráse ti o ti kú ni agbegbe naa .

Awọn ikọ  ọmọ ogun ati ara ilu ti o farapa nibi isẹle naa ni wọn ti gbe lọ si ile-iwosan fun itọju.

 

 

Abdulrafiu Kehinde

Leave A Reply

Your email address will not be published.