Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Àjọ NCDC ní kò sí ẹni tó ní ààrùn korona lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà báyìí

Ademọla Adepọju

41

Àjọ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà,iyẹn Nigeria Centre for Disease Control (NCDC)  ti ní kò sí kò sí ẹni tó ní ààrùn COVID-19 lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà báyìí lọ́jọ́ Ajé, osù kọkànlélógún, ọdún, 2021.

Ajọ NCDC lo sọ eleyii lori itakun ayelujara wọn. https://covid19.ncdc.gov.ng/

“Ni bayii  iye awọn to ti ni aarun COVID 19 jẹ́, ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-le-ni-màrún-din-ni -ọgọ́jọ (167,155) nigba ti iye awọn ti o ti gba iwosan jẹ ẹgbàájì-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-din-ni-ọ́ta (163,540)  awọn eniyan ti ie wọn jẹ ẹ̀ta-din-ni-okòó-le-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá ( 2,117) lo ti jẹ Ọlọrun nipe.

Leave A Reply

Your email address will not be published.