Take a fresh look at your lifestyle.

Àìlówó kọ́ ni ìsoro ilẹ́ Afirika-Ọbasanjọ

Ademọla Adepọju

40

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà tẹ́lẹ̀rì, Olusẹgun Ọbasanjọ ti ní kì í ṣe àìlówó tàbí àìní àwọn ohun àlùmọ̀ọ́nì ló ń ṣe ìdíwọ́ fún ìdàgbàsókè ilẹ̀ Afirika bí kì í e  ìsòro  àìmọ líló àwọn ohun elo àlùmọ̀ọ́n yìí.

Obasanjo , ti igbakeji asoju ẹka to n mojuto ọrọ isẹ akanse ni ajọ agbaye , ọjọgbọn Abdoulaye Bathily soju rẹ nibi ifilọlẹ  ẹgbẹ ti yoo maa se Ifọrọwerọ  nipa ominira   Iṣọkan ilẹ̀ Afirika, to waye ni ipinlẹ Edo, lorilẹ ede Naijiria, salaye pe ilẹ Afirika gbọdọ maa samulo awọn ohun alumọọni wọn fun idagbasoke ẹkun wọn.

Aarẹ wa rọ awọn ilẹ Afirika lati mojuto bi awọn eniyan to yẹ ki wọn maa mu idagbasoke ba ilẹ Afirika se n fi orilẹ ede Afirika silẹ lọ si oke okun.

Aarẹ Ọbasanjọ ni alaga fun ẹgbẹ  Coalition for Africa’s Development (CoDA) .

Leave A Reply

Your email address will not be published.