Take a fresh look at your lifestyle.

Aarẹ Buhari kí ààrẹ tuntun fún orílẹ̀ èdè Iran kú orí-ire

Ademọla Adepọju

46

Ààrẹ orílẹ̀ èdè  Nàíjíríà, Muhammadu Buhari ti sàpéjúwe pé ètò ìdìbò tí  wọ́n fi yan ààrẹ tuntun fún orílẹ̀ èdè  Iran, Ebrahim Raisi , ti fi ìfẹ́ ti àwọn ènìyàn ní sí ètò ìjọba tiwa–ń-tiwa hàn .

Nigba ti aarẹ n sọrọ niluu Abuja lọjọ Aje , aarẹ ni  “Raisi yẹ fun  bo se jawe olubori ninu eto idibo aarẹ ọhun.”

Adari orilẹ ede Naijiria tun tẹsiwaju pe  “Eto ijọba tiwa-n-tiwa  maa n fun awọn oludibo ni anfaani lati tun awọn asoju wọn yan lọna irọrun .”

Aarẹ  Buhari wa rọ gbogbo ọmọ orilẹ ede Iran lati se atilẹyin fun  Raisi ki o baa le se aseyege ti alakan n  sepo lọna ati gbogun ti ajakalẹ aarun COVID-19 to n ba orilẹ ede naa wọya ija.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.