Take a fresh look at your lifestyle.

WỌN TI SUN EJỌ́ EVER GREEN-SUEZ CANAL SÍWÁJÚ

Ademọla Adepọju

33

Ile-ẹjọ Egypt ti sun ẹjọ ọkọ oju omi nla kan ti o di oju omi okun suez , lati je ki awọn  osisẹ oju omi ṣe ayẹwo lori bi wọn yoo san owo-gba mi-binu pada sapo wọn.

Ile-ẹjọ to wa ni  ilu Ismailia sọ pe ọjọ kerin osu keje ni wọn yoo da ejọ naa.

Adajọ agba, KHALED ABU BAKR sọ fun ile-ẹjọ pe awọn osise naa n wo n kan ti ile-ẹjọ fẹ se lori nnkan ti awọn ti wọn ni ọkọ oju omi naa se, bi oko oju omi nla ti o tobi julọ ni agbaye se  fa idiwọ ni apa kan ibi ti omi okun canal naa wa .

Orile-ede Naijiria ati awọn ti won ni ile-ise Japan’s shoei Kisen Kaisha Ltd, naa setan lati fi  okẹ aimọye millionu naira ran wọn lọwọ. Igbimo SCA naa ti beere fun ọkẹ  aimoye millionu naira lati fi ra awọn ohun to baje nigba ti oko oju omi naa subu ati lati fi san owo  fun  awọn ti wọn sisẹ lori atunse re.

 

 

 

Hamzat Roshidat Damola

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.