Take a fresh look at your lifestyle.

ÀTÚNSE TI WÀ LÓRI ÈTO INÁ MÒNÀMÓNÁ

Ademọla Adepọju

62

Ibùdó iná mònàmóná tí ó tóbi jùlọ ní orílé èdè naijiria ( EGBIN POWER PLC) ti se eto ọkẹ aimoye billionu naira lati le mu idagbasoke ba ina monamona, , ni eyi lati tun lee mu igbeeru ba ina mọnamọna anilẹ Afirika.

Amọsa ,ọkẹ aimọye gbese ti wọn jẹ le  se idiwọ lati maa jẹ ki wọn ri awọn  ohun elo ti wọn beere fun, ki asiko ti wọn fẹ bere ise na to to.

Ile-ise mọna mọna ti a mọ si, EGBIN POWER PLC,  n gbero lati seto bi wọn yoo se pese opo ina monamona keji, nipase mimu igbeeru ba  gaasi naa ko le se afikun si ina monamona, wọn si tun sọ pe ipele akọkọ ina mọna mọna yoo bere isẹ ni ọdun to n bọ.

Ajọ ti o n mojuto tita awọn ile isẹ ijọba ti n dabaa lati ta ọpa ayelujara  ki wọn le dakoowo ti o je ki agbara ina monamona  pọ si.

Amọsa, aarẹ  Muhammadu Buhari  ti pinnu  lati mu ilosiwaju ba  ina monamona lorilẹ ede Naijiria.

 

 

 

Hamzat Roshidat Damola

Leave A Reply

Your email address will not be published.