Take a fresh look at your lifestyle.

Àtúnse ètò ọrọ̀ ajé ní ààrẹ Buhari ń mójútó-Lai Mohammed

46

Mínísítà fún ètò ìròyìn àti àsà lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Lai Mohammed, ti ní àtúnse ètò ọrọ̀ ajé, pàápàá julọ̀, ìdàgbàsókè ètò okòòwò alábọ́dé  ni ìjọba  ààrẹ  Muhammadu Buhari ń mojuto.

Minisita sọrọ yii niluu Abuja lọjọ Abamẹta nibi  ipatẹ ọja tiwa-n-tiwa  ọlọjọ marun un ti wọn pari .

Minista tun tẹsiwaju pe lara eto ti wọn ti la silẹ fun ayẹyẹ ajọyọ ọgọta ọdun ti orilẹ ede Naijiria gba ominira ni idije arosọ fun awọn ọ̀dọ́ orilẹ ede yii ati ipatẹ ọja tiwa-n-tiwa.

lara awon ohun ti wọn yoo maa gbe jade nibi ipatẹ ọjà tiwa-n-tiwa ni ọkọ̀ Kona ti wọn se lorilẹ ede Naijiria  ati awọn ọkọ̀ ti yoo maa lo ina mọna-mọna .lara awon ti o wa pẹle minisita fun eto iroyin ati asa , Lai Mohammed ni minista ipinlẹ  fun eto okoowo ati ile-isẹ ,, Mariam Katagum.

Leave A Reply

Your email address will not be published.