Take a fresh look at your lifestyle.

Mi ò ní kàárẹ̀ láti máa wá rere gbogbo ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà-Buhari

Ademọla Adepọju

117

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Muhammadu Buhari ti fọkàn gbogbo ọmọ orílẹ̀ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà balẹ̀ pé ohun ti ṣe ìpinnu láti  tẹ̀síwájú nípa ìpinnu tí ìjọba rẹ̀ ti sètò láti se lọ́dún 2015.

Aarẹ sọrọ yii lọjọ Ẹti nile aarẹ to wa niluu Abuja nigba ti o n tẹwọgba awọn ọmọ ẹgbẹ alatileyin fun   Muhammadu Buhari ati Osinbajo  ( Muhammadu Buhari and Osinbajo Dynamic Support Group) lasiko ti wọn n se ifilọlẹ iwe apilẹko ti wọn pe ni  – ( Aseyọri ijọba Muhammadu Buhari laarinọdun marun un ( A Compendium of 5-Year Achievements of President Muhammadu Buhari’s Administration from 2015 – 2020).

Aarẹ wa gbosuba fun ẹgbẹ naa nipa atilẹyin  ati igbiyanju  wọn lati gbe iwe apilẹkọ naa jáde, ni eyi ti o sọ nipa isẹh ribiribi ti ijọba rẹ ti gbe se.

Oludari ẹgbẹ ọhun, Usman Ibrahim,ni  iwe apilẹkọ naa sọ nipa isẹ́ ribi-ribi ti ijọba aarẹ Buhari ti gbese  nipa eto ọrọ̀ ajé, ọkọ oju irin,gbigbogun ti iwa ibajẹ , eto idagbasoe ati bẹẹ bẹẹ lọ.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.