Take a fresh look at your lifestyle.

Kenneth Kaunda di olóògbé, ààrẹ Buhari sèdárò ikú adarí orílẹ̀ èdè Zambia

Ademọla Adepọju

115

Ààrẹ Muhammadu Buhari  ti sàpéjúwe olùdàsílẹ̀  àti  ẹni tí ó wà lẹ́yìn òmìnira fún orílẹ̀ èdè Zambia,Kenneth Kaunda  gẹ́gẹ́ bí akínkanjú  àti adárí orílẹ̀ èdè àgbáyé , tí ó fẹ́ràn orílẹ̀ èdè àti àwọn ènìyàn rẹ̀.

Njgba ti aarẹ n sọrọ nipa Kaunda ti o di oloogbe ni ọmọ  ọdun mẹtalelọgọrun (97), aarẹ sọ pe  “O jẹ iaylẹnu fun mi , nigba ti mo gbọ nipa iku,Kenneth Kaunda , mo mọ̀ nipa awọn eto idagbasoke ti o ti ṣe fun idagbasoke orilẹ ede Zambia  ati ni ilẹ̀  Afirika lapapọ.”

Aarẹ Buhari tun sọ pe , A ko le tete  gbagbe  bi Kaunda ṣe pese  fun aabo fun awọn onija ominira ati awọn to n tako iwa ẹlẹyamẹya a ti wọn sa kuro  lati South Africa ati orilẹ ede Rhodesia. tẹlẹri ”

Arẹ  Buhari  ba ẹbi, ijọba ati awọn neiyan orilẹ ede Zambia daro iku oloogbe naa.

Leave A Reply

Your email address will not be published.