Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-ẹ̀kọ́ ọmọ ogun ojú- omi , Naval Desert Warfare Institute yóò wà ní ìpínlẹ̀, Kano.

Ademọla Adepọju

192

Adárí ilé-isẹ́ ómo ogun ojú omi orilẹ ede Naijiria , Awwal Zubairu Gambo  ti ni ilé-ẹkọ ti ọmọ ogun oju omi , Naval Desert Warfare Institute ,yoo wa ni ipinlẹ Naval , Kano.

Ezekobe, sọrọ yii lasiko ti oun ati ikọ rẹ yọju si gomina ipinlẹ Kano,Abdullahi Umar Ganduje ni ọfisi rẹ to wa ni ipinlẹ Kano lọjọRu.

Ezkobe  wa beere fun ilẹ̀ lorukọ ẹgbẹ awọn aya  ọmọ  ogun oju omi ,Naval Officers Wives Association (NOWA) fun ilé iwosan.

O wa gbosuba fun gomina ipinlẹ Kano  fun eto idagbasoke to ti se ni ipinlẹ naa.

Ganduje  naa wa gbosuba fun gudu-gudu meje yaya mẹfa ti  ile-isẹ ikọ ọmọ ogun naa n ṣe lati ti o ti wa ni ipinlẹ Kano.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.