Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí darí ìpàdé ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀

Eyitayọ Fauzuat Oyetunji

181

Ààrẹ  Mùhámmádù Bùhárí ń  darí ìpàdé   Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ lóríí ayélujára ní Ìyẹ̀wù àpèjọ arábìnrin àkọ́kọ́, ní Víllà, Àbújá.

Lara awọn ti o  fojuhan  nibi ipade ọhun ni, Igbakeji aarẹ Yemi Osinbajo, Akowe fun Ijọba apapọ, Boss Mustapha ati ọga agba fun Awọn oṣiṣẹ  aarẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari. Diẹ ninu awọn aworan  ọhun ni o wa nisalẹ yii.

 

 

 

 

 

 

 

Awọn miiran ti o tun pẹlu wọn ni minisita fun Idajọ, Abubakar Malami ati  ti Iṣẹ ati ibugbe, Babatunde Fashola, imọ ẹrọ ati amayedẹrun , Ogbonnaya Onu ati  ti olu ilu , Mohammed Bello.

Ọga agba fun awọn oṣiṣẹ apapọ , Dokita Folasade Yemi-Esan ati awọn minisita miiran n kopa ninu ipade minisita ọlọsọọsẹ lati ọpọlọpọ awọn ibujoko wọn ni ilu Abuja.

Awọn alaye lẹkunrẹrẹ  nigbamii…

 

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.