Take a fresh look at your lifestyle.

A ti yọ àwọn ènìyàn tó lé ní ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá kúrò nínú òsì

Ademọla Adepọju

0 88

Ààrẹ  Muhammadu Buhari ti ní ìjọba òun ti yọ awọn ènìyàn tó lé ní ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá kúrò nínú òsì lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà.

Ààrẹ  Muhammadu Buhari sọrọ yìí lori  ẹ̀rọ mohun -maworan lati sami ayẹyẹ ajọdun ọdun eto ijọba tiwa-n-tiwa ti ọdún 2021.

Aarẹ tun sọ pe bo tilẹ jẹ pe  ajakalẹ aarun  COVID-19  sẹlẹ  ati bi awọn eniyan se n pọ si lorilẹ ede yii sibẹ, ijọba oun tubọ sa ipa rẹ lati mu igbaye-gbadun rọrun fun awọn ọmọ orilẹ ede Naijiria..

Aarẹ tun ni ijọba oun fun awọn eniyan to le ni ẹgbẹrun kan ni ẹgbẹrun marun un naira lati din ipenija ti aarun ajakalẹ da silẹ lorilẹ ede yii.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.