Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ sàánú àwọn àtìpó ti ogun lé kúrò nílùú wọn-Abẹnugan ,Ahmad Lawan

109

Abẹnugan ilé ìgbìmọ̀ asòfin ,Ahmad Lawan  ti rọ gbogbo  àwọn adarí tí wọ́n jẹ́  ọmọ orílẹ̀  èdè Nàíjíríà láti máa sàánú àwọn àtìpó, ti ogun lé kúrò nílùú wọn,.

Asofin  Lawan, sọrọ yii lọjọ Ẹti  lasiko ti ikọ awọn asofin  lọ si Wasa  niluu Abuja, ni Gusu orilẹ ede Naijiria  fun ajọyọ ayẹyẹ ọdun keji ti awọn asofin ti lò.

Asoju igbimọ asofin tun fun awọn atipo ọhun ni  ẹbun owó  miliọnu mẹwaa naira pẹlu ounjẹ  ati awọn ohun elo míràn .

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.