Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ máa sàánú àwọn olè, ajínigbé,ọ̀daràn, ẹ ṣe wọ́n bí ọsẹ se ń sojú-Buhari

Ademọla Adepọju

245

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Muhammadu Buhari, ti pàsẹ fún gbogbo àwọn ilé-isẹ́ agbófinró àti ilé-isẹ́ ọmọ ogun orílẹ̀ èdè yìí láti máa sàánú àwọn olè, ajínigbé  ọ̀daràn àti àwọn tí wọ́n ń da omi àlàáfíà orílẹ̀ èdè yìí rú pàápàá jùlọ ní ìlà, ìwọ oòrùn Àríwá orílẹ̀ èdè yìí.

Aarẹ sọrọ yii lasiko ifọrọwerọ pẹlu ile-isẹ mohun -maworan (Arise Television,) Aarẹ tẹsiwaju pe “ A ti pasẹ fun ile-isẹ ologun ati awọn agbofinro lati maa foju aanu woàwọn olè, ajínigbé  ọ̀daràn àti àwọn tí wọ́n ń da omi àlàáfíà orílẹ̀ èdè yìí rú pàápàá jùlọ ní ìlà, ìwọ oòrùn Àríwá orílẹ̀ èdè yìí. Ẹyin , ẹ maa wo ohun ti yoo sẹlẹ laarin awon ọsẹ yii, ẹ o ri awọn iyatọ kan ti yoo maa sẹlẹ .”

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.