Take a fresh look at your lifestyle.

Olùsọ́ àgùtàn àti olùdásílẹ̀ ìjọ Church of All Nations (SCOAN),pásítọ́ TB Joshua ti kú.

Ademọla Adepọju

61

Olùsọ́ àgùtàn ati oludasilẹ ìjọ Church of All Nations (SCOAN),pásítọ́  Temitọpe  Balogun ti a mọ si ,TB Joshua ti jẹ́ Ọlọ́run nípè.

Ààrẹ  orilẹ ede Naijiria,  Muhammadu Buhari  ti  ba ẹbi ati gbogbo ọmọ ijọ  Synagogue, Church of All Nations (SCOAN)  kẹ́dùn  lori ikú olùsọ́ àgùtàn ati oludasilẹ SCOAN ,pásítọ́  Temitọpe  Balogun ti a mọ si ,TB Joshua .  .

Ninu atẹjade kan ti olrnalọwọ aarẹ lori iroyin ati ikede,Femi Adesina gbé jade lọjọ Aiku.

Aarẹ tun wa ba ijọba  ati awọn ọmọ ipinlẹ  Ondo kẹdun lori iku olusọ agutan ọhun, , aarẹ wa gbadura pe ki Ọlọrun tẹ́ pasitọ TB Joshua si afẹfẹ ire.

 

.

Leave A Reply

Your email address will not be published.