Take a fresh look at your lifestyle.

Àtúnṣe òfin:Ẹ gba àwọn tó wà nílùú òkèèrè láàyè láti dibò-Dabiri-Erewa

Ademọla Adepọju

66

Ẹ̀tọ́ àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà láti  máa dìbò láti ibikíbi tí wọ́n bá wà , ni wọ́n tún ti  gbé wá sí  ibi ìjíròrò ita gbangba  láti ṣe àt́unse sí òfin ọdún 1999.

Alaga ajọ to n mójútó ọ̀rọ̀ to jẹ mọ ti ilẹ̀ okeere,NIDCOM, Abike Dabiri-Erewa, lo dari awọn ọmọ orilẹ ede Naijiria to n gbe ilẹ̀ okeere wa si ibi ijiroro ọhun, ni eyi ti igbakeji abẹnugan ile igbimọ asofin,Ovie Omo-Agege ń dari rẹ̀.

Alaga ajọ naa tun wa tẹnumọ pe o le ni orilẹ ede mọ́kàndínlọ́gọ́fà (119) ti wọn ti n jẹ ki awọn ọmọ orilẹ ede wọn ń dibo lati ibikibi ti wọn ba wa nilẹ okeere.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.