Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19: Àwọn ènìyàn márùndínlọ́gbọ̀n míràn lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà tún ti ní ààrùn Korona

182

Àjọ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ ààrùn lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà tún ti kéde pé àwọn ènìyàn márùndínlọ́gbọ̀n míràn tún ti ní ààrùn Koona, ti a mọ si,Covid-19 lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà.

Nibayii apapọ gbogbo awọn  to ti ni aaru ọhun lorilẹ ede Naijiria ti jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-din-ni-ojì (166,560),  nigba ti àwọn to ti  gba ìwòsàn  jẹ ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-din-ni-mẹ̀fà-din-ni-ọ̀ta (159,946 ) nigba ti awọn ọ̀kan-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá (2,099)   padanu ẹmi wọn.

Awọn ipinle ti awọn aarun  naa ti jade niwọny: Lagos-10, Taraba-9, Kaduna

Leave A Reply

Your email address will not be published.