Take a fresh look at your lifestyle.

Àtúnṣe yóò dé bá ìlànà ètò ojú ọjọ́ – Buhari

Ademọa Adepọju

243

Ààrẹ  Muhammadu Buhari ti fọwọ́sí àtúnse  ìlànà ètò ojú ọjọ́  fún orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.

Minisita fún ètò àyíká , ọmọwe Muhammad Mahomod tun sọ pe eto ilana tuntun yii  yoo tun ni “Adehun ti aarẹ Muhammadu Buhari fọwọsi lọdun 2015  ní Paris, yoo wa ninu atunṣe tuntun ọhun , ni eyi to ni ṣe pẹlu ojú ọjọ́.”

 Mahomodtun sọ pe eto ilana tuntutn fur oju ọjọ yii yoo bẹ̀rẹ̀ lọdun  2021 sí ọdun 2030.

Minisita wa dupẹ lọwọ aarẹ bo sẹ fọwọsi eto ilana fun ojú ọjọ́ , ni eyi to wa ni ibamu ilana ajọ agbaye.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.