Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí pé àpèjọ Ìpàdé Ìgbìmọ̀ Aṣojú lórí ayélujára

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

156

Ààre Mùhámmádù Bùhárí ń ṣe àpèjọ ìpàdé  Ìgbìmọ́ Aláṣẹ lórí ayélujára nì yàrá Àpèjọ  arábìnrin àkọ́kọ́,villa, Abuja.

Awọn ti o wa ni ijoko nibi apejọ ọhun nii Igbakeji Aare Yemi Osinbajo, Akọwe fun Ijọba apapọ , Boss Mustapha ati ọga agba fun awọn oṣiṣẹ aarẹ , ọjọgbọn Ibrahim Gambari.

Awọn miiran to tun wa nijoko ni  minisita fun iroyin  ati Aṣa, Lai Mohammed, Isuna owo, Zainab Ahmed, Idajọ, Abubakar Malami, iṣẹ ati eto ibugbe  Babatunde Fashola ati Niger Delta, Godswill Akpabio ati awọn miran.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.