COIVD-19:Àwọn ènìyàn mẹ́tàlé-nígba tún ti ní ààrùn Korona lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà
Ademọla Adepọju
Àjọ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ ààrùn lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà,Nigeria Centre for Disease Control, NCDC, ti tun sọ pe àwọn ènìyàn mẹ́tàlé-nígba tún ti ní ààrùn Korona lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà. Nibayii, iye awọn to ti ni aarun COVID-19 ti jẹ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-din-ni-èjì-le-ni-ọ́rin ( 166,518).
Iye awọn to ti gba iwosan ti jẹ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrún-le-ni-ọ̀kẹ́-mèje-abọ-din-ni-ọ̀kan-din-ni -okòó-le-nigba (158,781) nigba ti awọn to ti pdaanu ẹ̀mí wọn jẹ́ ọ̀kan-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá( 2,099) .
Awọn ipinlẹ ti aarun COVID-19 ti jẹyọ niyii; Benue-178, Lagos-10, Ondo-6, FCT-4, Kaduna-4 ati Plateau-1.
Leave a Reply