Take a fresh look at your lifestyle.

Inú ààrẹ Buhari bàjẹ́ lórí ikú Ahmed Gula

89

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti fi àìdùnnú rẹ hàn lórí ikú  Ahmed Gula, tí àwọn agbébọn pa ní  ìlú Owerri tó jẹ́  olú ìlú ìpínlẹ̀ Imo.

Lasiko ti aarẹ Buhari n fesi  lọjọ Aiku  nipa isẹlẹ buruku ọhun aarẹ ni : “Inu mi bajẹ nipa bi awọn eniyan buruku se pa Gulak, awọn eniyan buruku se eyi lati da omi alaafia , ìsọ̀kan orilẹ ede Naijiria rú. 

“E jẹ sọ pe , ko si eniyan tabi ẹgbẹ  ti o lọwọ ninu isẹlẹ ibi yii ti yoo lọ ni alaafia. A o lo gbogbo ohun ti o wa ní ìkáwọ́ wa lati ri i pe gbogbo awọn onísẹ́  ibi yii jẹya labẹ ofin.” 

Aarẹ  Buhari wa ba ẹbi , ọrẹ ati ijọba ipinlẹ Adamawa kẹdun lori iku Ahmed Gula ọhun..” 

Leave A Reply

Your email address will not be published.