Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19: Àwọn ènìyàn mẹ́tàlélọ́gọ́rin míràn tún ti ní Corona lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà

Ademọla Adepọju

134

Àjọ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ ààrùn lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Nigeria Centre for Disease Control,  NCDC tún ti fi síta lórí ẹ̀rọ Twitter wọn pé àwọn ènìyàn mẹ́tàlélọ́gọ́rin míràn tún ti ní Corona lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà.

Ni bayii iye aw on ti wọn ti ni aarun COVID-19 lorilẹ ede Naijiria wa jẹ́ ẹgbàáta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-le-ni-mẹrinlá-din-ni-ọ́ta-le-nigba(166,254) nigba ti awọn ti o ti gba iwosan jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin-le-ni-ọ̀kẹ́-mèje-abọ-din-ni-mẹrinlá-din-ni-ọ́ta-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta(156,546) nigba ti iye awọn to ti padanu ẹmi wọn jẹ ọ̀kan-din-ni-ojì-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá(2,071)

Awọn ipinlẹ ti aarun COIVD-19 naa ti jẹyọ  ni : Lagos-25, Ondo-22, Rivers-6, Akwa Ibom-3, Kaduna-3, Kwara-2, Ebonyi-1 and FCT-1.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.