Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Àwọn ènìyàn márùndínláàdọ́ta tún ti ní Corona lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà

201

Àwọn ènìyàn márùndínláàdọ́ta tún ti ní Corona lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà bayii, ni eyi to ti jẹ ki iye awọn to ni COVID-19 jẹ́ ẹgbàáta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-le-ni-ọ̀kan-le-ni-àádọ́wá(166,191).

Gẹgẹ bi  ajo to n gbogun ti ajakalẹ aarun lorilẹ ede Naijiria , NCDC se  kede rẹ lori ẹrọ Twitter wọn pe awọn ipinlẹ ti aarun naa gbe jẹyọ ni :

“Lagos-27 Rivers-14 Kaduna-2 Jigawa-1 Ekiti-1.”

Bakan naa, iye awọn ti o ti gba iwosan jẹ, ẹgbàáta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-le-ni-ọ̀kan-le-ni-àádọ́wá (156,535) nigba ti iye awọn ti o ti padanu ẹmi wọn jẹ́ ọ̀kan-din-ni-ojì-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá (2,071).

Leave A Reply

Your email address will not be published.