Take a fresh look at your lifestyle.

Ọ̀gágun Farouk Yahaya di adarí tuntun fún ilé-isẹ́ ológun orílẹ̀ èdè Nàíjíríà

Ademọla Adepọju

153

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà , Muhammadu Buhari  ti yan ọ̀gágun Farouk Yahaya gẹgẹ bi i adarí tuntun fún ilé-isẹ́ ológun,orílẹ̀ èdè Nàíjíríà  láti rọ́pò olóògb́e ọ̀gágun   Ibrahim Attahiru ti o padanu ẹmi rẹ̀ nínú ìjàḿbà ọkọ̀ bàálù tó wáyé́ ní ìpínlẹ̀ Kaduna lọ́sẹ̀ tó kọjá .

Leave A Reply

Your email address will not be published.