Take a fresh look at your lifestyle.

Nàíjíríà leè fara káásá nínú wàhálà tó bá ń sẹlẹ̀ lórílẹ̀ èdè libya-Buhari

0 417

Ààrẹ orìlẹ́ èdè Nàíjíríà , Muhammadu Buhari ti ní ohun tó bá dé bá ojú ti dé bá imú, nítorì náà,  wàhálà tó bá n sẹlẹ̀ lórílẹ̀ èdè Libya, di dandan kí ó kan orìlẹ́ èdè Naijiria, nítorí  pé ́ orìlẹ́ èdè Chad ati Niger tí wọ́n súnmọ́ orìlẹ́ èdè Naijiria bi isan ọrùn mú  àlà pẹ̀lú orìlẹ́ èdè Libya.

Aarẹ sọrọ yii lasiko to n tẹwọgba alaga igbimọ ijọba ti orilẹ ede Libya,Mohammed Younis Menfi, lọjọRu, niluu Abuja.

Mohammed Younis Menfi naa tun sọ pe, nibayii , awọn ti ni ij,oba kan lorilẹ ede Libya ati pe awọn ko ni pẹ bẹrẹ eto idibo laipẹ.

O tẹsiwaju pe orilẹ ede Naijiria ati Libay jọ ni itan iwasẹ kan naa ati awọn ohun alumọọni bi i epo rọbi, ohun ọgbin ati bẹẹbẹẹ lọ.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button