Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19: Àwọn ènìyàn méjìdínláàdọ̀ta míràn tun tí ní ààrùn lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà

Ademọla Adepọju

185

Àwọn ènìyàn mọ́kàndínláàdọ̀ta míràn tun tí ní ààrùn Corona  lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà bayii.. Ni bayii iye awọn to ti ni aarun COVID ti jẹ ẹgbàáta-le -ni -ọ̀kẹ́- mẹ̀jọ-leni meérinlá-din-ni -àádọ́jọ   (166,146) nigba ti awọn ti eniyan ti iye wọn jẹ  ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin-le-ni-ọ̀kẹ́-mèje-abo -din- ni -ọ̀kan-din-ni-ojì -din -ni -ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta ( 156,529 ) ti gba iwosan.A won  eniyan ti  o ti padanu ẹ̀mí wọn jẹ́ (2,071)

Awọn ipinlẹ ti aarun COVID-19 ti jẹyọ ni ; Lagos-22, Rivers-11, Enugu-11, Kaduna-2,  FCT-1 ati  Gombe-1.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.