Take a fresh look at your lifestyle.

Àyàfi kí ẹ sàtúnṣe sí òfin Nàíjíríà, tí ẹ ò bá fẹ́ kí Nàíjíríà, túká- Ike Ekweremadu

Ademọla Adepọju

116

Igbákejì abẹnugan fún ilé ìgbìmọ̀ asòfin orílẹ̀ èdè Nàíjíríà  tẹ́lẹ̀rí , tí ó tún jẹ́ alága fún ìgbìmọ̀ tó ń mójútó àtúnṣe òfin  fún iwọ̀ oòrùn orílẹ̀ èdè yìí, asofin Ike Ekweremadu ti pè fún àtúnṣe òfin orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.

Ekweremadu sọrọ yii pẹlu awọn akọroyin ni gbọngan ijiroro  gbangba fun atunṣe ofin ọdun 1999 ni  eyi to waye ni  iwọ-oorun ipinlẹ Enugu .

O tẹsiwaju pe atunse ofin ti waye ni awọn orilẹ ede kan ti wọn n dojukọ  iru awọn ipenija bawonyi.

A ti ri iru awọn orilẹ ede ti wọn ti la iru ipenija ti a n dojukọ bawọnyi kọjá, àwọn bi i orilẹ ede  Kenya, Brazil, abbl, ohun ti wọnṣ ni lati ṣe atunse si ofin orilẹ ede wọn, o se ni laanu e wọn ko gba atunse ofin ti a ṣe wa nibẹ” .

 

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.