Take a fresh look at your lifestyle.

Inú igbákejì ààrẹ, Osinbajo bàjẹ́ lórí ikú adarí ilé-isẹ́ ológún àti ikọ̀ ọmọ ogun rẹ̀

Ademọla Adepọju

133

Inú gbákejì ààrẹ orilẹ̀ èdè Nàíjíríà, ọ̀jọ̀gbọ́n, Yemi Osinbajo bàjẹ́ lásìkò tó gbọ́ nípa ìjàm̀bá ọkọ̀ bàálù ológun , ní èyí tí adarí ilé-isẹ́ ológun orilẹ̀ èdè Nàíjíríà,ọ̀gágun Ibrahim Attahiru àti ikọ̀ ọmọ ogun rẹ̀ pàdánù ẹ̀mí wọn.

Ninu atẹjade kan ti oluranlọwọ igbakeji aarẹ,Osinbajo,Laolu Akande  gbe jade lati fi kẹdun iku awọn akọni ọhun .

igbakeji aarẹ tun sọ pe ” “Mo darapọ  mọ aarẹ orilẹ ede Naijiria, Muhammadun Buhari lati kẹdun pẹlu awọn ẹbi , ọrẹ ati akẹgbẹ awọn akọni ti wọn padanu ẹmi wọn ninu ijamba ọkọ baalu ológun .Mo gbadura pe Ọlọrun yoo tẹ àwọn akọni ọhun si afẹfẹ ire. Orilẹ ede Naijiria ko si ni gbagbe awọn akọni ọhun”.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.