Take a fresh look at your lifestyle.

ilé-isẹ́ ètò ìwádìí ìjàm̀bá ni yóò máa darí ìwádìí ìjàm̀bá ọkọ̀ òfurufú ológun

AdemọlaAdepọju

81

Ilé-isẹ́ to n mojuto  ètò ìwádìí lori awọn ìjàm̀bá to ba waye  lorilẹ ede Naijria ni  ile-isẹ ológun ojú afẹfẹ ti pasẹ̀ fún pe, awọn ni yóò máa darí ìwádìí ìjàm̀bá ọkọ̀ òfurufú ológun to waye ni ipinlẹ Kaduna lọjọ Ẹti, ni eyi ti adari ile-isẹ ologun orilẹ ede Naijiria ati ikọ ọmọ ogun rẹ padanu ẹ̀mí wọn..

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.