Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19: Àwọn ènìyàn márùndínlọ́gbọ̀n míràn tún ti ní ààrùn Corona

Ademọla Adepọju

219

Àjọ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ ààrùn lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà, (The Nigerian Centre for Disease Control, NCDC,) ti tún kéde síta pé àwọn ènìyàn márùndínlọ́gbọ̀n míràn tún ti ní ààrùn Corona báyìí.

Iye awọn to ni aarun COVID-19 ti di ẹgbàáta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-din-ni-ọ̀kan-le-ni-okòó ( 165,979) nigba ti awọn to ti gba iwosabn jẹ́ ẹgbàáta-le-ni-ọ̀kẹ́-mèje-abọ-le-ni-èjì-le-ni-ojì-din-ni -ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta (156,468) nigba ti iye awọn eniyan ti o ti padanu ẹ̀mí wọn jẹ́ ẹ̀ta-le-ni-ojì-din-ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá ( 2067)

Leave A Reply

Your email address will not be published.