Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé ìgbìmọ̀ asojú-sòfin bẹnu àtẹ lu bí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn se ń kú lórílẹ̀ èdè yìí

Ademọla Adepọju

111

Ilé ìgbìmọ̀ asojú-sòfin  ti  bẹnu àtẹ lu bí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀  àwọn ènìyàn se ń kú lórílẹ̀ èdè yìí, pẹ̀lú ọ̀kẹ́ àìmọye owó lọ́dọọdún tí wọn ń bù fún gbogbo ilé-ìwòsàn   tó wà ní jáke-jado orilẹ ede Naijiria .

Algba igbimọ asoju sofin lori eto ilera  lo sọrọ  yii pẹlu awọn akọroyi niluu Abuja.

ile igbimo NASS however noted that Universal Health Coverage cannot be achieved through the exclusive National Health Insurance Scheme currently run by the federal government.

Alaga igbimọ asofin lori eto ilera , Ibrahim Oloriegbe  naa ninu ọrọ rẹ pe ile igbimọ asofin koro oju si bi awọn eniyna se n ku lorilẹ ede Naijiria nipasẹ eto ilera to mẹhẹ.

O tẹsiwaju pe ile -isẹ ma-dami-dofo to n mojuto eto ilera ,National Health Insurance Scheme, NHIS  gbọdọ tun tẹpẹlẹ mọ isẹ wọn lati wi pe pupọ ninu ọmọ orilẹ ede Naijiria lo jẹ anfaani eto ilera mma-dami-dofo yii.

Alaga ile igbimọ asoju  lori eto ilera  Tanko Sununu naa tun sọ pe atunse gbọdọ ba ofin to fẹsẹmulẹ ile-isẹ ma-dami-dofo lori eto ilera , ki o lee rọrun fun gbogbo omọ orilẹ ede Naijiria lati jẹgbadun eto ọhun.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.