Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Àwọn  ènìyàn mọ́kàndí́nláàdọ́ta (49) lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà,tun ti ni aarun Korona

Ademọla Adepọju

164

Àwọn  ènìyàn mọ́kàndí́nláàdọ́ta (49) lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà, tun ti ni aarun Korona ìyẹn COVID-19. báyìí.

Ajọ to n gbogun ti ajakalẹ aarun lorilẹ ede Naijiria , Nigeria Centre for Disease Control NCDC, lo kede rẹ lori ẹro  Twitter wọn lọjọBọ..

Awọn ipinlẹ ti aarun naa gbe jẹyọ ni ipinlẹ Eko -21, Rivers-16, FCT-5, Kano-3, Akwa Ibom-2, Ebonyi-1, Ekiti-1.

Ni bayii, awọ eniyan to ti ni aarun COIVD 19 lorilẹ ede Naijiria ti jẹ ẹgbàáta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-din-ni-ọ̀kan-din-ni-ọgọ́rùn, nigba ti awọn eniyan to ti gba iwosan  si jẹ ẹgbàáta-le-ni-ọ̀kẹ́-mèje-abọ-le-ni-ọ̀kan-le-ni-ojì-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta (156,459) and awọn eniyan to ti padanu  ẹmi wọn si jẹ ẹ̀ta-le-ni-ojì-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá.

(2,067) .

Leave A Reply

Your email address will not be published.