Take a fresh look at your lifestyle.

Bàálù ikọ̀ ọmọ ogun orí afẹ́fẹ́ gbiná nílùú Kaduna

113

Ile -isẹ ologun oju afẹfẹ,  Nigerian Air Force (NAF) ti kede pe bàálù  wọń gbiná  nibi ti ko jinna pupọ ṣi papa ọkọ ofurufu to wa niluu Kaduna.

Alukoro fun ile-isẹ ọhun , ọgagun  Edward Gabkwet lo sọrọ yii niluu Abuja lori ẹrọ Twitter  rẹ lasale  ọjọ Ẹti..

Amọsa , ko si ẹni ti  o mọ ohun ti o faa ti baalu naa ṣe gbina .

Ẹkunrẹrẹ iroyin naa n bọ laipẹ.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.