Take a fresh look at your lifestyle.

Ọ̀jọ̀gbọ̀n Ibrahim Abubakar di adarí  tuntun Fafiti, ilu London,University College, London (UCL)

Ademọla Adepọju

0 297

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti kí Ọ̀jọ̀gbọ̀n Ibrahim Abubakar, onímọ̀ àgbáyé nínú  àjàkálẹ̀ àarun  kú orí- re lóri bí wọ́n se yàn án gẹ́gẹ́ bíi adarí  tuntun ti Ile-ẹkọ giga Fafiti, ilu London,University College, London (UCL) ti ẹ̀ka  ìmọ̀-ìjiǹlẹ̀ nípa ìlera ènìyàn.

Aarẹ sọrọ yii ninu atẹjade kan ti oluralọwọ rẹ lori ikede ati iroyin Garba Shehu gbe jade lọjọ Aje.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button