Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ènìyàn mọ́kàndínláàdọ́rin míràn tún ti ní ààrùn Covid-19 lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà

Ademọla Adepoju

102

Àwọn ènìyàn mọ́kàndínláàdọ́rin míràn tún ti ní ààrùn Covid-19 lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà gẹ́gẹ́ bí àjọ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ ààrùn lórílẹ̀ ede Naijiria se kéde rẹ̀.

Ajọ naa tun sọ pe iye awọn eniyan to ti ni aarun Corona lorilẹ ede Naijiria wa jẹ́ ẹgbàáta-le-ni -ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-din ni-mèjì-le- ni -okòó (165,778 ) nigba ti iye awọn enioyan to ti gba iwosan jẹ́ ẹgbàáta-le-ni-ọ̀kẹ́-mèje-abọ-le -ni-màrún-din-ni-okòó-le-ni-irinwó (156,415) nigba ti iye awọn eniyan to ti padanu ẹmi wọn jẹ́ mẹ̀ta-le-ni-ojì-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá (2,067).Awọn ipinlẹ ti wọn ti ni aarun COVID naa ni :.

Ondo-35( Marundinlogoji)
Lagos-30-( ọgbọ̀n)

Leave A Reply

Your email address will not be published.